Baba Agbomola

Baba Agbomola Chief (Dr) Agbomola Native Healing.

A ku ojumo, a siku isinmi oni o. Talomo oruko ewe yi. ?
01/09/2024

A ku ojumo, a siku isinmi oni o. Talomo oruko ewe yi. ?

AGBO GENERAL INFECTION.Bara kan, epa ikun di e, baka di e, kanafuru di e, ati kafura pelebe kan. A o ha epo ara egusi ba...
23/07/2024

AGBO GENERAL INFECTION.
Bara kan, epa ikun di e, baka di e, kanafuru di e, ati kafura pelebe kan. A o ha epo ara egusi bara, a o gesi wewe a o ge baka ati epa ikun naa si wewe. A o san awon eroja yi dada, a o ko won sinu ike tabi/keg a o fi kafura pelebe kan si pelu kanafuru a o bu omi si i. Leyin ojo keta, mimu laraaro.

OGUN IBON TODAJU SAKA.Enikeni ti o bafi ogun yi ja ole, tabi fini omo yoruba lara yi o di omi mo lara.A o lowa agbon kan...
23/06/2024

OGUN IBON TODAJU SAKA.
Enikeni ti o bafi ogun yi ja ole, tabi fini omo yoruba lara yi o di omi mo lara.
A o lowa agbon kan ti o jabo lati ori igi fun rara e, a o sa epo ara re Kuro. A o lu oju kan ninu oju meta ti o ni. A o wa etu ibon original die, a o wa ota (c@rtridge) kan, a o wa ota ibon oyinbo () kan. A o fi hand saw ge ota ibon oyinbo ati ti c@rtridge a o daa Sinu paper pelu etu ibon a o ro ebu meteta yi sinu iho agbon a o de agbon yi a o gbesi inu ikoko tuntun ni igun ile fun ojo meta. Ti o badi ojo keta a o mu omi agbon yi pelu egbogi inure.

23/06/2024

Aku ojumo, asiku ojometa.
Ona atije, atimu konidi mowa lagbara Olorun.

EYONU ASINAKoro inu agbalumo lopolopo, atare kan, Pelu ewe ewuro oojo. A o jo gbogbo re, a o lo kuna dada. A o dasinu oy...
18/05/2024

EYONU ASINA

Koro inu agbalumo lopolopo, atare kan, Pelu ewe ewuro oojo. A o jo gbogbo re, a o lo kuna dada. A o dasinu oyin gidi a o mala laaro kutu kia to soro si enikeni fun ojo meta lera. Adura wa yi o gba o.

OSE ASINA FUN ONISE OWO TABI ONISOWO. Eran elede die, Pali s.t luois sugar kan,  kafura pelebe meji ati ose oyo. A o gun...
16/02/2024

OSE ASINA FUN ONISE OWO TABI ONISOWO.

Eran elede die, Pali s.t luois sugar kan, kafura pelebe meji ati ose oyo. A o gun eran elede yi kuna daada. A o gun kafura pelebe, sugar ati ose pomo eran elede, a o ko sinu ike funfun leyin ojo keta wiwe pelu adura laaro kutu ki oorun o toyo. Yi o bawalaramu.

AGBO ISOYE (MEMORY LOST HERB) Epo ogede paaranta dudu ni iwonba Pelu alum die, a o ge epo ogede dudu si wewe, a o ko sin...
15/02/2024

AGBO ISOYE (MEMORY LOST HERB)
Epo ogede paaranta dudu ni iwonba Pelu alum die, a o ge epo ogede dudu si wewe, a o ko sinu ike olomori a o fi alum die si. A o ro omi si fun ojo kan, mimu die die laaro ati lale.

ASEJE OSHO INU (SPIRITUAL CONCONSION).This ASEJE (spiritual conconsion) is what one can use to compete for a chieftancy ...
27/01/2024

ASEJE OSHO INU (SPIRITUAL CONCONSION).

This ASEJE (spiritual conconsion) is what one can use to compete for a chieftancy title or to become a king of a town. or to compete for a political post. Or to win a very big contracts, or promotion at your work place.

Ingredients are as follows:
Ewe èlà mẹta, ewé abamoda mẹta, ewé Alukerese mẹta, ewé ṣawerepèpè itakun mẹta, ewé tàgíìrì mẹta, falling ripe palmkannel seed mẹsan, àkuko adìye nlá tó tí n kọ ẹyọkan, atare (201), iyere (201), with the currency speding in one's country. You will grand these leaves together, with atare and iyere (201) you will put 9 pieces of palmkanel inside the conconsion pot. You will kill the c**k, let a (man) cut it into 9 pieces while a (woman) should cut it into 7 pieces, pour coconut water in the conconsion pot, and put the pot on fire and cook. once it's done, put the conconsion pot at the corner of your room, with (do as I say authority) in your front, you will naked yourself if you are ready to eat this conconsion, you will sit and face the corner of the room where you put this conconsion and the do as I say authority. As you are eating the conconsion you will be praying and be mentioning all what you wants.

23/01/2024
OSE  ASIRI BIBO TI ENIYAN FIN SAN GBESE. Ewe ejirin, ewe anu, eyin adiye ibile oojo (1), ose oyo pelu sugar onigun. A o ...
23/01/2024

OSE ASIRI BIBO TI ENIYAN FIN SAN GBESE.
Ewe ejirin, ewe anu, eyin adiye ibile oojo (1), ose oyo pelu sugar onigun. A o gun ewe ejirin, ewe anu, sugar onigun papo mo ose oyo. Leyin eyi a o fo eyin adiye ibile oojo sii, a o fi po papo, a o fa sinu ike funfun, leyin ojo keta odi wiwe Pelu adura. Yi o bawa laramu .

OSE ASINAEwe ewuro ojoo, epo obo pelu ose to wunwa. (Soap of our choice) ao gun papo ti yio kuna dada. Ao ma buwe pelu a...
09/01/2024

OSE ASINA
Ewe ewuro ojoo, epo obo pelu ose to wunwa. (Soap of our choice) ao gun papo ti yio kuna dada. Ao ma buwe pelu adura.

OGUN ISETOA o ja ewe ejirin ti yio po die, a o san, leyin eyi a o se Lori ina fun bi ogbon iseju (30minutes)  to ba tutu...
04/01/2024

OGUN ISETO

A o ja ewe ejirin ti yio po die, a o san, leyin eyi a o se Lori ina fun bi ogbon iseju (30minutes) to ba tutu tan a o ma a mu ni glass cup kan laaro ati laale fun ojo meje.

Address

Ijebu Ode

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Baba Agbomola posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share